Ìkéde Pàtàkì: Isé Àkànse Asòfin Àgbà, Yùnûs Akíntúndé
IKEDE PATAKI
OMI GIDI!!! ISE AKANSE
ASOFIN AGBA, YUNUS AKINTUNDE
Omi yalayolo ti nlo Ina igbalode itansan oorun fun igbadun omoniyan kaakiri gbogbo agbegbe l’abe isakoso Asoju sofin Agba, Yunus Akintunde ti Aarin gbungbun Ipinle Oyo tun ti koja lo si Ijoba Ibile Lagelu ati Akinyele bayi o!
Eleyi waye ninu ose yi lehin ti won ti se aseyori ise nla akanse Omi yalayolo fun agbegbe mokanla ni Ijoba Ibile Ona Ara lenu loolo yi.
Won ti bere si nii fi Ero igbalode gbe kangadero.
Pelu idunnu ati Ayo ni o waye kaakiri gbogbo agbegbe ti awon olugbe l’omode l’agba si n gbo’suba fun Asofin Agba Senator Yunus Akintunde fun ise takun takun ti nse kaakiri fun igbaye gbadun Ara Ilu.
E ku ise o! A moo loore o! Tanantana Yunus!, Asofin Agba Maa Se Pupo siii!!!
Kunle OLATUNJI,
Fun Apapo Akoroyin.